Nipa

Picturing Nigeria je iwadi nipa awon ilu ni orile ede Nigeria. Enikeni ti o ba fe le fi awon aworan Nigeria han nibi.

A fe fi awon iriri ojojumo Nigeria han. Nipa sise eyii, yiya awon aworan yii ati fifi won han le tubo pese itumon ti o jinle lori awon iriri wonyii.

Ero wa nipe, ti a ba fi awon aworan yii si ori website yii won yo le je

ona miran ti a le fi wo Nigeria. Website naa yo je ki owun elo ti yo je ki awon aworan yii je owun ijiroro fun gbogbogbo. Ireti wa ni wipe, ise yi ko ni d’opin ni ibi bayii, amo yo maa tesiwaju. Itesiwaju yii yo si je ki ise naa maa tubo ni itumo sii.

Iwo naa le nipa ninu ise yii! Fun wa ni awon ilu re ti o ba ti ya. Te ibi lati bere. Te ibi lati bere si fi awon aworan re han tabi ki o ti "Bere" ni isale lati wo awon aworan awon elegbe re. Ti o ba si fe, o le damonran lori awon aworan to awon elomiran ti ya kale.

Bere

Lati ko iwe si wa, lo adresi yii. Ma fi aye kankan si arin re